Jump to content

First Lady of the United States

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
First Lady of the United States
title, ipò
LábeeFirst Lady Àtúnṣe
Jé arafirst family of the United States Àtúnṣe
Ìbèrè30 Oṣù Igbe 1789 Àtúnṣe
Native labelFirst Lady of the United States Àtúnṣe
Official residenceWhite House Àtúnṣe
Position holderMelania Trump Àtúnṣe
Orílè-èdèÀwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà Àtúnṣe
Applies to jurisdictionÀwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà Àtúnṣe
Official websitehttps://www.whitehouse.gov/about-the-white-house/first-families/ Àtúnṣe
Bibliographybibliography of United States presidential spouses and first ladies Àtúnṣe
Ní àtòjọlist of first ladies of the United States Àtúnṣe

Obìnrín Àkọ́kọ́ ti Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà tàbí Ìyá Àkọ́kọ́ ti Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (FLOTUS) ni oyè tí ìyàwó Ààrẹ Amẹ́ríkà sábà máa ń ní, èyí tí ó ní ṣé pẹ̀lú àkókò tí Ààrẹ wà ní ipò.Ìyá Àkọ́kọ́ ti Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà jẹ́ àlejò sí Ilé Ààrẹ.

Ìyàwó Ààrẹ Amẹ́ríkà ló sábà máa ń gba ipò yìí, àmọ́ nígbà míì, orúkọ oyè náà ni wọ́n máa ń lò fún àwọn obìnrin tí kì í ṣe ìyàwó Ààrẹ, bí àpẹẹrẹ nígbà tí Ààrẹ bá jẹ́ ọ̀dọ́mọbìnrin tàbí opó, tàbí nígbà tí ìyàwó Ààrẹ kò bá lè ṣé iṣẹ́ Ìyá Àkọ́kọ́.

Ìyá Ààrẹ kì ń ṣé òṣìṣẹ́ tí wọ́n yàn; kò ní ipò ìjọba, bẹ́ẹ̀ ni kò ní owó oṣù. Àṣà ni pé, obìnrin ààrẹ kì ń ṣiṣẹ́ níta nígbà tí wọ́n bá ń ṣiṣẹ́, bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn kan ti ní iṣẹ́ ṣùgbọ́n wọ́n ti fi owó tí wọ́n ń rí fún àjọ ìrànwọ́.

Melania Trump ni obìnrin àkọ́kọ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí tó ti ń ṣé ipò náà fún ìgbà kejì láti ọdún 2025.

Àwọn obìnrin àkọ́kọ́ Amẹ́ríkà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Orukọ yìí ní àwọn tó sìn gẹ́gẹ́ bí obìnrin àkọ́kọ́, láìka bóyá wọ́n ti ṣègbéyàwó sí ààrẹ tàbí wọn kò tíì ṣègbéyàwó, àti àwọn tí àwọn ìkànnì White House kà sí obìnrin àkọ́kọ́.

POTUS
No.

Àwòrán Orúkọ Ìgbà lóri ìpò Ààrẹ
(ọkọ wọ́n, tàbí èyíkéyìí nínú ìbílẹ̀ wọ́n)
1 Portrait of Martha Washington Martha Washington
June 2, 1731 – May 22, 1802
(ọmọ ọdún 70)

[1]
April 30, 1789
–
March 4, 1797
George Washington
2 Portrait painting of Abigail Adams Abigail Adams
November 22, 1744 – October 28, 1818
(ọmọ ọdún 73)

[2]
March 4, 1797
–
March 4, 1801
John Adams
3 Portrait painting of Martha Jefferson Martha Jefferson Randolph
September 27, 1772 – October 10, 1836
(ọmọ ọdún 64)
March 4, 1801
–
March 4, 1809
Thomas Jefferson
Bàbá rẹ̀
4 Portrait painting of Dolly Madison Dolley Madison
May 20, 1768 – July 12, 1849
(ọmọ ọdún 81)

[3]
March 4, 1809
–
March 4, 1817
James Madison
5 Portrait painting of Elizabeth Monroe Elizabeth Monroe
June 30, 1768 – September 23, 1830
(ọmọ ọdún 62)

[4]
March 4, 1817
–
March 4, 1825
James Monroe
6 Portrait engraving of Louisa Adams Louisa Adams
February 12, 1775 – May 15, 1852
(ọmọ ọdún 77)

[5]
March 4, 1825
–
March 4, 1829
John Quincy Adams
7 Emily Donelson

June 1, 1807 – December 19, 1836
(ọmọ ọdún 29)

[6]

March 4, 1829
–
November 26, 1834
Andrew Jackson
Ègbọ́n rẹ̀
Sarah Jackson

July 16, 1803 – August 23, 1887
(ọmọ ọdún 84)

[7]

November 26, 1834
–
March 4, 1837
Andrew Jackson
Bàbá ọkọ rẹ̀
8 Ààyé ṣ'òfò March 4, 1837
–
November 27, 1838
Martin Van Buren
Ìyáwò rẹ̀ kú
Portrait painting of Angelica Singleton Van Buren Angelica Van Buren
February 13, 1818 – December 29, 1877
(ọmọ ọdún 59)

[8]
November 27, 1838
–
March 4, 1841
Martin Van Buren
Bàbá ọkọ rẹ̀
9 Portrait painting of Anna Tuthill Harrison Anna Harrison
July 25, 1775 – February 25, 1864
(ọmọ ọdún 88)

[9]
March 4, 1841
–
April 4, 1841
William Henry Harrison
Portrait painting of Jane Irwin Harrison Jane Harrison
July 23, 1804 – May 11, 1847
(ọmọ ọdún 42)

March 4, 1841
–
April 4, 1841
William Henry Harrison
Bàbá ọkọ rẹ̀
10 Portrait painting of Letitia Tyler Letitia Tyler
November 12, 1790 – September 10, 1842
(ọmọ ọdún 51)

[10]
April 4, 1841
–
September 10, 1842
†
John Tyler
Portrait painting of Priscilla Cooper Tyler Priscilla Tyler
June 14, 1816 – December 29, 1889
(ọmọ ọdún 73)

[11]
September 10, 1842
–
June 26, 1844
John Tyler
Bàbá ọkọ rẹ̀
Portrait painting of Julia Tyler Julia Tyler
May 4, 1820 – July 10, 1889
(ọmọ ọdún 69)

[12]
June 26, 1844
–
March 4, 1845
John Tyler
11 Portrait painting of Sarah Polk Sarah Polk
September 4, 1803 – August 14, 1891
(ọmọ ọdún 87)

[13]
March 4, 1845
–
March 4, 1849
James K. Polk
12 Portrait painting of Margaret Taylor Margaret Taylor
September 21, 1788 – August 14, 1852
(ọmọ ọdún 63)

[14]
Maachị 4, 1849
–
Julaị 9, 1850
Zachary Taylor
13 Portrait painting of Abigail Fillmore Abigail Fillmore
March 13, 1798 – March 30, 1853
(ọmọ ọdún 55)

[15]
July 9, 1850
–
March 4, 1853
Millard Fillmore
14 Engraving of Jane Pierce Jane Pierce
March 12, 1806 – December 2, 1863
(ọmọ ọdún 57)
[16]
March 4, 1853
–
March 4, 1857
Franklin Pierce
15 Portrait photograph of Harriet Lane Harriet Lane
May 9, 1830 – July 3, 1903
(ọmọ ọdún 73)

[17]
March 4, 1857
–
March 4, 1861
James Buchanan
Ègbọ́n rẹ̀
16 Portrait photograph of Mary Lincoln Mary Lincoln
December 13, 1818 – July 16, 1882
(ọmọ ọdún 63)

[18]
March 4, 1861
–
April 15, 1865
Abraham Lincoln
17 Portrait engraving of Eliza Johnson Eliza Johnson
October 4, 1810 – January 15, 1876
(ọmọ ọdún 65)

[19]
April 15, 1865
–
March 4, 1869
Andrew Johnson
18 Portrait photograph of Julia Grant Julia Grant
January 26, 1826 – December 14, 1902
(ọmọ ọdún 76)

[20]
March 4, 1869
–
March 4, 1877
Ulysses S. Grant
19 Portrait photograph of Lucy Hayes Lucy Hayes
August 28, 1831 – June 25, 1889
(ọmọ ọdún 57)

[21]
March 4, 1877
–
March 4, 1881
Rutherford B. Hayes
20 Portrait photograph of Lucretia Garfield Lucretia Garfield
April 19, 1832 – March 14, 1918
(ọmọ ọdún 85)

[22]
March 4, 1881
–
September 19, 1881
James A. Garfield
21 Portrait of Mary Arthur McElroy Mary McElroy
July 5, 1841 – January 8, 1917
(ọmọ ọdún 75)

[23]
September 19, 1881
–
March 4, 1885
Chester A. Arthur
Ègbọ́n rẹ̀
22 Portrait of Rose Cleveland Rose Cleveland
June 13, 1846 – November 22, 1918
(ọmọ ọdún 72)
March 4, 1885
–
June 2, 1886
Grover Cleveland
Ègbọ́n rẹ̀
Portrait of Frances Cleveland Frances Cleveland
July 21, 1864 – October 29, 1947
(ọmọ ọdún 83)

[24]
June 2, 1886
–
March 4, 1889
Grover Cleveland
23 Portrait of Caroline Harrison Caroline Harrison
October 1, 1832 – October 25, 1892
(ọmọ ọdún 60)

[25]
March 4, 1889
–
October 25, 1892
†
Benjamin Harrison
Portrait of Mary Harrison McKee Mary Harrison McKee
April 3, 1858 – October 28, 1930
(ọmọ ọdún 72)
October 25, 1892
–
March 4, 1893
Benjamin Harrison
Bàbá rẹ̀
24 Portrait of Frances Cleveland Frances Cleveland
July 21, 1864 – October 29, 1947
(ọmọ ọdún 83)

[24]
March 4, 1893
–
March 4, 1897
Grover Cleveland
25 Portrait of Ida McKinley Ida McKinley
June 8, 1847 – May 26, 1907
(ọmọ ọdún 59)

[26]
March 4, 1897
–
September 14, 1901
William McKinley
26 Portrait of Edith Roosevelt Edith Roosevelt
August 6, 1861 – September 30, 1948
(ọmọ ọdún 87)

[27]
September 14, 1901
–
March 4, 1909
Theodore Roosevelt
27 Portrait of Helen Taft Helen Taft
June 2, 1861 – May 22, 1943
(ọmọ ọdún 81)

[28]
March 4, 1909
–
March 4, 1913
William H. Taft
28 Portrait of Ellen Wilson Ellen Wilson
May 15, 1860 – August 6, 1914
(ọmọ ọdún 54)

[29]
March 4, 1913
–
August 6, 1914
†
Woodrow Wilson
Portrait of Margaret Woodrow Wilson Margaret Wilson
April 16, 1886 – February 12, 1944
(ọmọ ọdún 57)

[30]
August 6, 1914
–
December 18, 1915
Woodrow Wilson
Bàbá rẹ̀
Portrait of Edith Wilson Edith Wilson
October 15, 1872 – December 28, 1961
(ọmọ ọdún 89)
[31]
December 18, 1915
–
March 4, 1921
Woodrow Wilson
29 Portrait of Florence Harding Florence Harding
August 15, 1860 – November 21, 1924
(ọmọ ọdún 64)

[32]
March 4, 1921
–
August 2, 1923
Warren G. Harding
30 Grace Coolidge Grace Coolidge
January 3, 1879 – July 8, 1957
(ọmọ ọdún 78)

[33]
August 2, 1923
–
March 4, 1929
Calvin Coolidge
31 Portrait of Lou Hoover Lou Hoover
March 29, 1874 – January 7, 1944
(ọmọ ọdún 69)

[34]
March 4, 1929
–
March 4, 1933
Herbert Hoover
32 Portrait of Eleanor Roosevelt Eleanor Roosevelt
October 11, 1884 – November 7, 1962
(ọmọ ọdún 78)

[35]
March 4, 1933
–
April 12, 1945
Franklin D. Roosevelt
33 Portrait of Bess Truman Elizabeth Truman
February 13, 1885 – October 18, 1982
(ọmọ ọdún 97)

[36]
April 12, 1945
–
January 20, 1953
Harry S. Truman
34 Portrait of Mamie Eisenhower Mary Eisenhower
November 14, 1896 – November 1, 1979
(ọmọ ọdún 82)

[37]
January 20, 1953
–
January 20, 1961
Dwight D. Eisenhower
35 Portrait Of Jaqueline Kennedy Jacqueline Kennedy
July 28, 1929 – May 19, 1994
(ọmọ ọdún 64)

[38]
January 20, 1961
–
November 22, 1963
John F. Kennedy
36 Portrait of Lady Bird Johnson Claudia Johnson
December 22, 1912 – July 11, 2007
(ọmọ ọdún 94)

[39]
November 22, 1963
–
January 20, 1969
Lyndon B. Johnson
37 Portrait of Pat Nixon Thelma Nixon
March 16, 1912 – June 22, 1993
(ọmọ ọdún 81)

[40]
January 20, 1969
–
August 9, 1974
Richard Nixon
38 Portrait of Betty Ford Elizabeth Ford
April 8, 1918 – July 8, 2011
(ọmọ ọdún 93)

[41]
August 9, 1974
–
January 20, 1977
Gerald Ford
39 Portrait of Rosalynn Carter Rosalynn Carter
August 18, 1927 – November 19, 2023
(ọmọ ọdún 96)

[42]
January 20, 1977
–
January 20, 1981
Jimmy Carter
40 Portrait of Nancy Reagan Nancy Reagan
July 6, 1921 – March 6, 2016
(ọmọ ọdún 94)

[43]
January 20, 1981
–
January 20, 1989
Ronald Reagan
41 Portrait of Barbara Bush Barbara Bush
June 8, 1925 – April 17, 2018
(ọmọ ọdún 92)

[44]
January 20, 1989
–
January 20, 1993
George H. W. Bush
42 Portrait of Hillary Rodham Clinton Hillary Clinton
Ọjọ́ìbí 26 Oṣù Kẹ̀wá 1947 (1947-10-26) (ọmọ ọdún 78)
[45]
January 20, 1993
–
January 20, 2001
Bill Clinton
43 Portrait of Laura Bush Laura Bush
Ọjọ́ìbí 4 Oṣù Kọkànlá 1946 (1946-11-04) (ọmọ ọdún 79)
[46]
January 20, 2001
–
January 20, 2009
George W. Bush
44 Portrait of Michelle Obama Michelle Obama
Ọjọ́ìbí 17 Oṣù Kínní 1964 (1964-01-17) (ọmọ ọdún 62)
[47]
January 20, 2009
–
January 20, 2017
Barack Obama
45 Photograph of Melania Trump Melania Trump
Ọjọ́ìbí 26 Oṣù Kẹrin 1970 (1970-04-26) (ọmọ ọdún 56)
[48]
Janu6 20, 2017
–
January 20, 2021
Donald Trump
46 Jill Biden
Ọjọ́ìbí 3 Oṣù Kẹfà 1951 (1951-06-03) (ọmọ ọdún 75)
[49]
January 20, 2021
–
January 20, 2025
Joe Biden
47 Melania Trump
Ọjọ́ìbí 26 Oṣù Kẹrin 1970 (1970-04-26) (ọmọ ọdún 56)
[48]
January 20, 2025
–
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Donald Trump

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ↑ "Biography of Martha Washington". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via National Archives.
  2. ↑ "Biography of Abigail Adams". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  3. ↑ "Biography of Dolley Madison". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  4. ↑ "Biography of Elizabeth Monroe". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  5. ↑ "First Lady Biography: Louisa Adams". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  6. ↑ "Emily Donelson" (in en). WHHA. https://www.whitehousehistory.org/bios/emily-donelson.
  7. ↑ "First Ladies Never Married to Presidents: Sarah Jackson". www.firstladies.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-10-12. Retrieved 2017-06-01. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  8. ↑ "First Lady Biography: Hannah Van Buren". National First Ladies' Library. Archived from the original on October 9, 2018. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  9. ↑ "Biography of Anna Harrison". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  10. ↑ "Biography of Letitia Tyler". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via National Archives.
  11. ↑ "Letitia Tyler Biography :: National First Ladies' Library". Firstladies.org. December 28, 1907. Archived from the original on September 30, 2018. Retrieved September 7, 2016. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  12. ↑ "Biography of Julia Tyler". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via National Archives.
  13. ↑ "First Lady Biography: Sarah Polk". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  14. ↑ "First Lady Biography: Margaret Taylor". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  15. ↑ "First Lady Biography: Abigail Fillmore". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  16. ↑ "First Lady Biography: Jane Pierce". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  17. ↑ "Biography of Harriet Lane". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via National Archives.
  18. ↑ "First Lady Biography: Mary Lincoln". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  19. ↑ "First Lady Biography: Eliza Johnson". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  20. ↑ "Biography of Julia Grant". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  21. ↑ "Biography of Lucy Hayes". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via National Archives.
  22. ↑ "First Lady Biography: Lucretia Garfield". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  23. ↑ "Mary Arthur McElroy, White House hostess for President Chester Arthur". loc.gov. Library of Congress. 1885. Retrieved 2 May 2017.
  24. 1 2 "Biography of Frances Cleveland". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via National Archives.
  25. ↑ "First Lady Biography: Caroline Harrison". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  26. ↑ "Biography of Ida McKinley". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via National Archives.
  27. ↑ "First Lady Biography: Edith Roosevelt". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  28. ↑ "First Lady Biography: Helen Taft". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  29. ↑ "Biography of Ellen Wilson". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via National Archives.
  30. ↑ "First Lady - Ellen Wilson". C-SPAN.
  31. ↑ "First Lady Biography: Edith Wilson". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  32. ↑ "Biography of Florence Harding". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via National Archives.
  33. ↑ "Biography of Grace Coolidge". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  34. ↑ "Biography of Lou Hoover". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  35. ↑ "First Lady Biography: Eleanor Roosevelt". National First Ladies' Library. Archived from the original on April 29, 2020. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  36. ↑ "Biography of Bess Truman". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  37. ↑ "First Lady Biography: Mamie Eisenhower". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  38. ↑ "Biography of Jacqueline Kennedy". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  39. ↑ "Biography of Lady Bird Johnson". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  40. ↑ "Biography of Pat Nixon". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  41. ↑ "Biography of Betty Ford". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  42. ↑ "Biography of Rosalynn Carter". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  43. ↑ "Biography of Nancy Reagan". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via NARA.
  44. ↑ "First Lady Biography: Barbara Bush". National First Ladies' Library. Archived from the original on March 3, 2009. Retrieved March 11, 2010. Unknown parameter |url-status= ignored (help); More than one of |archiveurl= and |archive-url= specified (help); More than one of |archivedate= and |archive-date= specified (help); More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  45. ↑ "First Lady Biography: Hillary Clinton". National First Ladies' Library. Archived from the original on April 14, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  46. ↑ "First Lady Biography: Laura Bush". National First Ladies' Library. Archived from the original on May 9, 2012. Retrieved March 11, 2010. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  47. ↑ "Biography of Michelle Obama". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2010 – via National Archives.
  48. 1 2 "First Lady Biography: Melania Trump". National First Ladies' Library. Archived from the original on August 10, 2020. Retrieved March 11, 2017. More than one of |accessdate= and |access-date= specified (help)
  49. ↑ "Biography of Jill Biden". whitehouse.gov. Retrieved March 11, 2021 – via National Archives.